Fáwêlì tí ó ní àmì òkè ( á,é,ë,í,ó,ö,ú) kìí bêrê õrõ ní ojúlówó Yorùbá A vowel with a high pitch sound ( ´ ) does not begin words in Yoruba.
à- àpò bag (-)
à-gbò àgbò ram (-)
à-gbê àgbë farmer (-)
a- abç razor a- awó guinea-fowl (re-re) (re-)
P
re
re
Iÿë ÿíÿe - Exercise
Owó wà nínú àpò yìí. There is money inside this bag.
Yoruba word list. Look up English equivalent. Àgbo, Agbo Àwo, Awo Abë Apó
Parí gbólóhùn Yorùbá yìí Complete this Yoruba sentence Ç** mélòó nìyìí? How many birds are these? Ç** m*** ni. They are seven birds.
Êkö Kçjô 8 Lesson Eight à, a - * a e ç i o ô u
Page 22
(Two over twenty)
Ojú-ìwé Kejìlélógún