ÀTÇ ÀWÒRÁN ÁLÍFÁBËÊTÌ YORÙBÁ YORÙBÁ ALPHABET PICTORIAL
Àtç àwòrán àwôn õrõ tí ó bêrê tí ó sì parí pêlú àwôn fáwêlì
Pictorial of words beginning and ending with the vowels
Aa Ee Çç Ii Oo Ôô Uu
nítorí pé àwôn fáwêlì ni ó þ ní àmì ohùn õrõ lórí.
since it is the vowels that are indicated with intonation marks.
Yoruba Alphabet Expanded Oral vowels Á á É é Ë ë Í í Ó ó Ö ö Ú ú A a E e Ç ç I i O o Ô ô U u À à È è Ê ê Ì ì Ò ò Õ õ Ù ù Fífi ìró ohùn köra lemölemö Tone Drill
Ó ÿe pàtàkì láti fi kíkö ìró ohùn lemölemö sí ètò êkö akëkõö alákõöbêrê láti ìbêrê. Õrànyàn ni ó jë láti fihàn pé ìro ohùn ÿe góþgó ní sísô èdè Yorùbá. Nýkan tí a þlépa nìyìí nínu apákan ìwé yìí tí ó têlé ojú ìwé yìí.
It is important to incorporate tone drills into the learning process for the beginning student right from the outset. This is necessary to underscore the centrality of tonal sounds in Yoruba discourse. The following sections of this book are designed to fulfill this purpose.
Page 13
Ojú-ìwé Kçtàlá