Môfölöjì Yorùbá Yoruba Morphology Ètò õrõ ni a þ Môfölöjì. Morphology is the structure of Ó ÿe pàtàkì láti ìmõ ó words. It is important to have a péye nípa ètò gígé çyô õrõ good knowledge of how a word êbù-êbù (sílébù) èdè Yorùbá is divided into its component parts nítorí çyô sílébù kõõkan (syllable) in Yoruba because each ni ó ní ìró ohùn tirê.
syllable has its own distinct pitch. Bátànì sílébù ìpilê mëta ni a fi þ Three basic syllable patterns are used hun õrõ Yorùbá.
in forming Yoruba words. Àwôn ni:
They are:
1 . ( F ) Fáwêlì ( V ) Vowel 2 . ( KF ) Köþþsónáýtì + Fáwêlì (CV) Consonant + Vowel 3 . (M m, N n) Sílébù Àránmúpè Syllabic Nasal V Vowel C  Consonant
F Fáwêlì K Könþsónáýtì
Môfölöjì Yorùbá Morphology
Page 10
Ojú-ìwé Kçwàá