À þ bá àwôn àmì ohùn mìíràn We do come across other intonation pàdé nínú àwôn ìwé Yorùbá marks in both old and modern day àtijö àti ti òde òní. Yoruba books. Àwôn tí ó ÿe gógó ni: The main ones are:
1 . Àmì fàágùn ( ~ ) A kìí lo àmì yìí mö nítorí pé kò wúlò. A ti fi lílo fàwêlì méjì tí õkõõkan ní àmì tirê dípò irú àwôn õrõ bëê. Fún àpççrç:
1 . The tilde ( ~ ) This sign is no longer in use because it is not useful. The use of two vowels, each with its own intonation mark is now used in such instances. e.g.:
õrùn can be
oòrùn o-ò-rùn sun tàbí / or òórùn ò-ó-rùn smell
2 . Àmì ohùn ìsàlê àti òkè àpapõ ( ˇ ) Ó dá mi lójú pé yóò ya àwôn òýkàwé wa lënu láti rí àmì tí ó ÿe àjèjì yìí lórí orúkô mi -
2 . The low-rising tone ( ˇ ) I am sure it will come as a surprise for readers of this book to see this unfamiliar accent mark on my name –
Ônäbàjò, Ônäyçmí - Ônàábàjò, Ônàáyçmí
A ÿe èyìí láti mú un rôrùn fún pipe orúkô náà bí ó ti tö báyìí
This is done to facilitate proper pronunciation of the name as
re--- , re--re- kì í ÿe / not ---, --re-
gëgë bí ogunlögõ ènìyàn ÿe þ pè é. Nípa ÿíÿe báyìí, a yçra fún lílo fáwêlì méjì fún orúkô náà. A tún lo àmì ohùn yìí nínú ìwé yìí fún nö¹bà 1
as many are wont to do. In doing this, doubling the vowel for the name is avoided. This accent mark is also used in this book for the number 1
Kïnní dípò / instead of Kìn-ìn-ní Àmì yìí kò wöpõ mö nínú àwon ìwé
Yorùbá.
This intonation mark is no longer in common use in Yoruba texts.
P
Ìró ohùn Phonology
Fonölöjì Yorùbá Phonology
Page 9
Ojú-ìwé Kçsàn-án