Ìró ohùn ni òpó èdè Yorùbá. The tone is the pillar of the Yoruba language. Ìró ohùn ni òpó èdè Yorùbá. The tone is the pillar of the Yoruba Ìró ohùn èdè ni à þ pé ni language. Phonology is the speech Fonölöjì. Ìró ohùn pàtàkì mëta sounds of a language. There are ni ó èdè Yorùbá. Àwôn three basic tones in Yoruba. They ni ohùn òkè, àárín àti ìsàlê. are the high, middle and low tones.
A fi àwôn àmì ohùn mëta yìí töka sí wôn.
These three accent marks are used to indicate them.
Àmì ohùn ìsàlê
( ` ) Grave sign
Àmì ohùn òkè
( ´ ) Acute sign Àmì ohùn àárín ( ¯ ) Mid tone sign
We do not usually place accent marks on words with a mid tone except in some instances when necessary.
A kì í sábà fi àmì sí orí õrõ olóhùn àárín àfi lëêkõõkan nígbà tí ó bá yç.
Fonölöjì Yorùbá Phonology
Ojú-ìwé Kçfà Page 6
Àkíyèsí
Note