Àwôn Fáwêlì Yorùbá Yoruba Vowels Oríÿìí àkójôpõ fáwêlì méjì There are two groups of vowels ni ó wà ní èdè Yorùbá. in Yoruba. 1 . Fáwêlì àìránmúpè 1 . Oral (Non-nasalized) vowels 2 . Fáwêlì àránmúpè 2 . Nasalised vowels 1 . Fáwêlì àìránmúpè - Oral vowels
2 . Fáwêlì àránmúpè - Nasalised vowels
Àkíyèsí: * ‘AN’ and ‘ÔN’ máa þ dún bákannáà. Note: ‘AN’ and ‘ÔN’ sound the same. Àkíyèsí: † Kò sí ‘EN’ tàbí ‘ON’ nínú õrõ Yorùbá àjùmõlò. Note:  There is no ‘EN’ or ‘ON’ in standard Yoruba vocabulary.
A a E e Ç ç I i O o Ô ô U u
*AN an ÇN çn IN in *ÔN ôn UN un
Fáwêlì Yorùbá Vowels
Ojú-ìwé Kçrin Page 4