Õrõ nípa Òýkõwé yìí Dökítà Adébùsölá Ônäbàjò Ônäyçmí jë Oníÿègùn Akunnilóorun -jí-ni ní Ilé-Ìwòsàn-
an
Royal Victoria ní ìlú
u
Bárì, Òýtáríò, Kánádà. Òun sì tún ni olùdarí ilé iÿë
ç
Bis Bus International tí wön þ ÿe àtêjáde êkö ìmõ lórísìírísìí õnà pëlú
u
Kõýpútà. Òun ni atêwéjade magasínìnnì onígbédègbëyõ Yo: ön , ön . Òun sì ni olùdásílê Çgbë Àjùmõka Yorùbá Ilê Àríwá Amëríkà èyí tí ó wà fún àýfàní àwôn ômô Yorùbá ní ìdálê láti jë kí ó rôrùn fún wôn láti kö èdè àti àÿà ìbílê
ç
wôn. Ìwé yìí ni àkökö nínú õwö àwôn ìwé tí a ÿe fún àwôn ômô çgbë yìí àti gbogbo àwôn tí ó jç níyàn láti kö èdè
e
Yorùbá káàkiri àgbáyé. A ÿe téèpù àti àwo kõýpútà tí a mõ sí CD-ROM ní ìbámu pêlú ìwé yìí láti túbõ mú êkö èdè yìí rôrùn fún wôn. Dökítà Ônäyçmí gbàgbö pé nípa mímú iÿë yìí wáyé, òun ti ÿe êtö
ô
tirê, ó wá yç kí àwôn òbí, aya tàbí ôkô àti àwôn tí ó wà ní ipò láti jë olùkö èdè
e
Yorùbá fún çlòmìíràn lo iÿë yìí fún ìdàgbàsókè àÿà ìbílê
ç
wa. Alágçmô ti bí ômô rê tán, àìmõö jó kù sí ôwö ômô rê. Dr. Adebusola Onabajo Onayemi is a specialist Anesthesiologist at the Royal Victoria Hospital, Barrie, Ontario, Canada. He is also the Executive Director of Bis Bus International, a Yoruba language Multimedia Publishing Company. He is the publisher of Yo : ön , ön . ( Know how to Write it , Know how to Read it ) a bilingual Yoruba/English magazine. He is the founder of Yoruba Readers’ Club of North America which was established to give Yoruba children in the diaspora a practical way to learn their language and culture. This is the first of a series of books designed for use by members of the club and indeed all who have the desire to learn Yoruba worldwide. There is also a companion tape and CD ROM to facilitate this process. Dr. Onayemi believes that in doing this work, he is fulfilling an obligation and the completion of the task now rests on the shoulders of parents, spouses and others who find themselves in position to teach Yoruba to use this resource to promote our common heritage.