Àkójôpõ õrõ létò çlëgbëmçgbë Vocabulary - in functional groups
Ebi Òýgbç Oúnjç Omi Ôbê Çran Çja Aÿô Fìlà ßõk òtò Bùbá Ìró Gèlè Bàtà Ìbõsê Pátá ßinmí Arúgbó Àgbà Õdö Ômödé Èwe Ôkùnrin Obìnrin Akô Abo
e-bi ò-ý-gbç o-ún- o-mi ô- -ran ç-ja a-ÿô -là  ÿò-- - ì- - - ì-- - ÿin- a--gbó à-gbà õ- ô-- è-we ô-kùn-rin o-bìn-rin a- a-bo
hunger thirst food water stew meat fish cloth,garment cap trousers, shorts tunic, blouse loin cloth head-tie shoe socks panties undergarment, chemise elderly person elder adolescent, youth, child youth, young folks, children, childhood man woman male female
Bàbá Ìyá  Õgbçni Ìyá-ààfin Abilékô Omidan Adélébõ Gbóná Tútù Löwörö Onílé Àlejò Õgá Ômô-iÿë Ômô-õdõ Ìbéèrè Ìdáhùn Èsì Òkè Ilê Ìbêrê Òpin Iwájú Êyìn (Êhìn) Iÿë Eré
- ì- õ-gbë-ni ì--à-a-fin a-bi-- o-mi-dan a- dé-- gbó- - -- o-- à-le- õ- ô--i-ÿë ô--õ- ì - b é - è - r è ì - d á - h ù n è - ò- i- ì-- ò-pin i-- ê-yìn (ê-hìn) i-s³e³; e-
father mother Mr. Mrs? Mrs Miss Miss? hot (adj) cold (adj) lukewarm host guest mas ter apprentice servant question answer reply top, hill, mountain ground beginning end front back work play
oókanléláàta
Page 66
(Four short of seventy) Ojú Ìwé Kçrìndínláàádörin