ÌJÔBA ORÍLÊ-ÈDÈ YORÙBÁ YORUBA KINGDOM Àwôn Yorùbá àti orílê-èdè wôn ti fún ìgbà pípë ÿíwájú ôdún 1000 A.D. (Çgbêrún ôdún lëyìn ikù Olúwa wa), èdè wôn ti fún, ó kéré tán, çgbêrún ôdún méjì. Àwôn êya ènìyàn mìíràn ó darapõ àwôn ômô ìbílê Yorùbá láàárín ôdún 700 sí 1000 A.D. kó oríÿìíríÿìí àÿà tuntun àti ìwà wá. ó tile õpõlôpõ ìtàn àdáyébá ni ó nípa ìpilêÿê ilê Yorùbá, èyí ó tayô a gbàgbö ni èyí ó Ilé-Ifê ni ilê ìbí wôn. Ilé- Ifê góþgó agbára ôdún 1300 nígbà a fi tánþganranÿe àwôn iÿë ônà. ßùgbön àkókò ìparí ôdún 1400, agbára ìjôba wale, ó fi àyè sílê fún ti ìjôba Õyö ó àríwá ilê Yorùbá. Jíjç ôba, êsìn àti iÿë ônà ÿíÿe jë pàtàkì ní àÿà ìbílê. Àÿàyìí sì fìdí mule ní àwôn orílê-èdè Karíbíánì àti Bràsíl níbití a kó o lô ní ìgbà òwò çrú ní àkókò ôgörùn-ún ôdún kejìdínlógún. Ôba Adésôjí Adérêmí tí a bí ní ôdún 1889 ni Ôõni kejìdínláàádöta Ilé-Ifê. Ó jôba láàárín ôdún 1930-1981. Ó ÿe akitiyan púpõ fún ìdàgbàsókè àÿà ìbílê Yorùbá. (My translation) The Yoruba people and their homeland took shape long before 1000 A.D. and their language is at least 2000 years old. Between 700 and 1000 A.D. an influx of immigrants merged with the Yoruba indigenes, injecting into the area new influences and ideas. Although several traditions concerning the origins of the Yorubas exist, one of the more commonly held belief is that Ife is their birthplace. Ife’s power reached its zenith around 1 3 0 0 A.D., culminating in the production of the famous Ife bronzes. However, towards the end of 1400 A.D., its political influence declined making way for the rise of the Oyo kingdom in Northern Yorubaland. Kingship, religion and craftsmanship have remained the main focus of Yoruba culture. Its cultural influence is remarkably strong in the Caribbean and Brazil where it was exported during the era of the slave trade in the eighteenth century. Born in 1889, Oba Adesoji Aderemi (1930-1981) was the forty-eighth Oni of Ife, who contributed immensely to Yoruba cultural development ( Federal Ministry of Information, Nigeria) Oba Adesoji Aderemi
Page 63
(Three over sixty) Ojú Ìwé Kçtàlélógójì