BÍßÖÕBÙ SÁMÚËLÌ ÀJÀYÍ CROWTHER BISHOP SAMUEL AJAYI CROWTHER Sámúëlì Àjàyí Crowther jë akëkõö kìn-ín-ní ní ilé-êkö gíga Fourah Bay ní orílê-dè Sàró. A bí i ní ìlú Òÿoògùn tí ó jë bíi ibùsõ mélòó kan sí ìlú Ìsëyìn ní apá guúsù rê. Àwôn akónilërú jí i gbé ní ôdún 1821 ÿùgbön a gbà a sílê lëhìn ôdún kan, ó sì di akëkõö ní ilé-ìwé ajíhìnrere ní 1823. Ó jë õmõwé tí ó mòye púpõ ní ilé-êkögíga (1828) ó sì di àlùfáa ní 1843. Nípasê iÿë àpilêÿe rê nínú ìrìnàjò rê sí agbègbè odò Ôya (1841) èyí tí ó lànà fún ìdásílê àwôn ilé iÿë ajíhìnrere ní Igbèbè, Ònìÿà, Lököja, Àkàsà, Bõní, Abönémà àti Búgúmà, a yàn án sí ipò Bíÿöõbù ‘Agbedeméjì Ìlà-Oòrùn Áfríkà títí kôjá ilê Ìjôba Ôbabìnrin Orílê-èdè Gêësì’ ní 1864. Ó tayô nínú iÿë ajíhìnrere, gbígbógun ti òwò çrú kíkó, àti iÿë olùköni (ó túmõ Ìwé Àdúrà sí Yorùbá, ó sì ÿe ìwé gírámà fún èdè Yorùbá, Íbò àti Nupé). Ó ní ìmõ iÿë ìwòsàn àti iÿë ilé kíkö. Ó kó ipá pàtàkì ninu akitiyan bí èdè Yorùbá ÿe di kíkô sílê. Ó di olóògbé ní ôjö kìn-ín-ní, ní oÿù kejìlá, ôdún 1891. (Ilé-iÿë aláÿç fún Ìkéde Ìròhìn Ìjôba àpapõ, nàìjíríà) (My Translation) Samuel Ajayi Crowther, the first student of Fourah Bay College, Sierra Leone, was born at Osogun a few kilometers south of Iseyin. He was kidnapped by slave traders in 1821, rescued a year later and became a mission school boy in 1823. He had a brilliant college career (1828) and became a clergyman (1843). As a result of his pioneering work in the Niger expedition (1841) which eventually led to the founding of missions in Igbebe, Onitsha Lokoja,Akassa, Bonny, Abonema and Buguma, he was nominated and ordained Bishop of Western Equitorial Africa beyond the Queen’s Dominion in 1864. He distinguished himself in such areas as evangelism, crusade against slave trade and education ( tra nslation of Prayer Book into Yoruba, authored grammar books for Yoruba, Ibo and Nupe languages ), medicine and architecture. He played a vital role in how the Yoruba language was first reduced to writing. He died on 1st December 1891. (Federal Ministry of Information, Nigeria) Bisoobu Samuel Ajayi Crowther Ayaworan Õgbëni Köládé Õshínöwõ- - (Two over sixty) Ojú Ìwé Kejìlélögöta Page 62