àÿà Yorùbá, okùn ó so çbí lágbára púpõ. Gbogbo çbí ni a ômô ìyá àti bàbá. Nítorí náà, ìtumõ pipe fún êgbön tàbí àbúrò ìyá àti bàbá àti ômô wôn. Bàbá àgbà, bàbá kékeré, ìyá àgbà, ìyá kékeré, êgbön à ti àbúrò ni gbogbo wôn.
In Yoruba culture, the family ties are very strong such that members of the extended family are usually regarded as belonging to the same nuclear family. There is no distinct translation for uncle, aunt, cousin - but they are junior or senior father or mother, brother and sister.
Bàbá
Father Obìnrin
Female
Ìyá
Mother Ôkùnrin Male
Êgbön
Older sibling Ômödébìnrin Girl
Àbúrò
Younger sibling Ômödékùnrin Boy
Àköbí
First born child Õdömôbìnrin Adolescent female
Àbíkëhìn Last born child Õdömôkùnrin Adolescent male Bàbá àgbà Grand father Àna In-law
Ìyá àgbà Grand mother Àfësönà
Fianceé
Ìyàwó
Wife
Ôkô
Husband
P
ÇBÍ FAMILY
Page 60
(Sixty) Ojú Ìwé Ôgöta