Ômô ôdún mëfà ni A. Ômôdékùnrin ni. Àpètán orúkô rê ni Aô. Ó tún þ jç A. Òun ni àbíkëhìn àwôn òbí rê.
Ade is six years old. He is a boy. His full name is Adeola. He is also known as Adeyemi. He is the last child of his parents.
Ó gbádùn eré böõlù orí pápá ní soma. Ó tún gbádùn eré hökì orí aìsì ní wínþtà. Ó máa þ gbá böõlù àgbájùsáwõn náà. ßùgbön ju gbogbo rê lô, ó gbádùn ìwé kíkà yálà lórí bébà ni o tàbí lórí êrô kõnýpútà.
He enjoys playing soccer in the summer. He also enjoys playing ice hockey in the winter. He also plays basketball. But above all he loves reading and writing either on paper or on the computer.
Ó wù ún láti gba àbúrò ôkùnrin.
He would love to have a junior brother.
A Ade
Page 59
(One short of sixty)
Ojú Ìwé Kôkàndínlögöta