Ômô ôdún mçjô ni O. Obìnrin ni òun náà. Àpètán orúkô rê ni Owafúnmi . Ó tún þ jë Owaÿeun.
Olu is eight years old She is also a girl. Her full name is Oluwafunmilayo. She is also called Oluwaseun.
Ó gbádùn dùrù títê àti ìwé kíkà. Êkö Èdè Farañsé ni ó fëràn jù. Ó máa þ bá àwôn çlçgbë rê gbá böõlù orí papa ní sömà. Ó tún gbádùn láti lúwêë.
She enjoys playing the piano and reading. French is her favorite subject. She plays soccer with her mates in the summer. She also likes to swim.
Oúnjç tí ó gbádùn jù ni dòdò àti möín-möín, ÿùgbön kò fi bögà, àkàrà òyìnbó àti àwôn oúnjç mçdçnmëêndên ÿiré.
Her favorite food is fried plantain and steamed bean cakes, but she does not joke with burger, cookies and other junk food.
O Olu
Page 58
(Two short of sixty)
Ojú Ìwé Kejìdínlögöta