Ômô ôdún mëwàá ni Ô. Àpètán orúkô rê ni Ôláþrewájú. Ó tún þ jë Ômöboöláþlé. Òun ni àköbí àwôn òbí rê.
Ola is ten years old Her full name is Olanrewaju She is also called Omobolanle. She is the first child of her parents.
Ìÿirò ni ó fëràn jú ní ilé- ìwé. Ó tún gbádùn Êkö Ìmö Sáyëýsì. Ó jáfáfá nínú orin kíkô àti dùrù títê. Ó máa þ jó ijó bàléè látijö, ÿùgbön nísisìyìí eré böõlù àgbájùsáwõn ni ó gbádùn láti máa gba pêlú àwôn çlçgbë rê.
Her favorite subject at school is Arithmetic. She also loves Science. She is proficient in music (singing and playing the piano). She did ballet dancing in the past but nowadays she loves playing basketball with her mates.
Ô
Ojú ìwé kçsàn-án
Ola
Page 57
(Three short of sixty)
Ojú Ìwé Kçtàdínlögöta