Akíntúndé ni orúkô rê Ômô ôdún méjìdínlógójì ni. Bàbá Ôlá ni àwôn çgbë rê þ pè e gëgë bí àÿà ìbílê nítorí pé Ôlá ni àköbí àwôn ômô rê. Iÿë olùkö ni ó þ ÿe. Ó gbádún ìwé kíkà àti ìwé kíkô. Oúnjç tí ó gbádùn jù ni êbà àti ôbê ilá. Ó tún fëràn iyán àti ôbê êfö. ßugbön iyán yìí kìí ÿe ti iÿu sísè tí a gún nínú odó. Iyán rírò ni. Yóò jçë bëê-bëê. Kìí jç bögà rárá
Ogbeni Ômôlúwàbí (Baba Ôlá)
Mr. Omoluwabi (Ola’s father)
Page 55
(Five short of sixty)
Ojú Ìwé Karùndínlögöta