Màmá Ôlá þ se oúnjç. Oúnjç õsán nìyìí. Êbà ni ó þ rò. Omi gbígbóná ni ó fi þ tç gaàrí tí yóò di êbà yìí.
Ola’s mother is preparing a meal. This is lunch. She is preparing eba She is mixing gaari in hot water then it becomes eba.
Ó ti se ôbê êfö sílê. Ó fi çja àti oríÿìíríÿìí çran síi. Àwôn ômô gbádùn oúnjç yìí ÿùgbön bí a bá bi wôn léèrè pé èwo ni ó dára jù nínú êbà àti bögà, wön á pariwo gèèè… wön á ní bögàààà…bögàààa…
She had cooked vegetable stew earlier. She put fish and assorted meat in it. The kids love this food, but if they are asked which one is better - eba or burger- they’ll shout gleefully ... and say burgerr...
Bàbá yóò tún wipe Bögà láàárõ, Bögà lösàn-àn, Bögà lálë – ó màÿe o!
Dad will say again Burger in the morning, burger in the afternoon, burger at night what a pity !
Aya Ômôlúwàbí (Màmá Ôlá)
Mrs Omoluwabi (Ola’s mother)
Page 54
(Four over fifty)
Ojú-ìwé Kçrìnléláàádöta