Çbí Ômôlúwàbí þ jç oúnjç àárõ The Omoluwabi family at breakfast
Bàbà gbádùn oúnjç a fi töô dàgbà. fëë gbàgbé ìgbà èwe rê. Ojoojúmö ni ó máa þ fún àwôn ômô pé: Bögà láàárõ, Bögà lösàn-àn, Bögà lálë ó màÿe o!
Dad likes the types of food he was brought up with. He does not want to forget his youth. He says to the kids everyday Burger in the morning, burger in the afternoon, burger at night.What a pity !
P
Page 53
(Three over fifty) Ojú-ìwé Kçtàléláàádöta