Ìkíni ní oríÿìíríÿìí ìgbà àti fún oríÿìíríÿìí ìÿêlê wöpõ ní àÿà Yorùbá. Díê nínú wôn nìyìí.
Greetings at various times for various occasions are very common in Yoruba culture. Here are some of them.
Ç káàárõ Good morning. Ç káàsàn Good afternoon. Ç kúrõlë Good evening.(early) Ç káalë Good evening. (late) Ó dàárõ Good night (till morning). Ó dàbõ Good bye. Ç káàbõ Welcome. Ç kúulé Greetings on meeting you at home. Ç kú àtijö Quite an age. Ç kú ôjö mëta Have not seen you in a while. ßé àlàáfíà ni? How are you? (are you in good health? Ç kú ìnáwó Greetings for spending money. Ç kú ìdìde Greetings for coming. Ç kú àfojúbà Greetings for seeing a visitor. Ç kú ìgbádùn Greetings for enjoying yourself.
P
ÌKÍNI GREETINGS à a á a-*a À A Á
Page 49
(One short of fifty)
Ojú-ìwé Kôkàndínláàádöta