Àkàyé Comprehension
Nísisiyìí, àsìkò tó láti lo àwôn êkö tí ç ti kö nínú ìwé yìí nínú àwôn ojù-ìwé yìí.
It is now time to put into practice what you have learnt in this book so far in the following pages.. We shall examine Sentences, Yoruba greetings, meet the Omoluwabi family and learn about Bishop Samuel Ajayi Crowther and some basic history of the Yoruba kingdom
Àmõyé Ise ya Ka àwôn gbólóhùn tí a kô sílê lësççsç. Reading exercises
Page 48
(Two short of fifty) Ojú-ìwé Kejìdínláàádöta