Êkö Ôgbõn 30 Lesson Thirty
S s ß ÿ
Page 47
(Three short of fifty) Ojú-ìwé Kçtàdínláàádöta
Ç Leg Çsê þ dún mí. My leg is hurting.
Êÿê Sin Êÿê ni irö pípa. Telling lies is a sin. Ôÿç Soap Ôÿç yìí dára. This soap is good. Aÿô Cloth Aÿô yìí dára This cloth is good
Õsê Week Õsê kan kò tó. One week is not enough. A Quarrel Asõ kò dára. Quarelling is not good. Òsì left Ôwö òsì mi niyìí. This is my left hand.
Àÿç Àÿç ni. It is an order.
Òÿì poverty Kò sí òÿì níbí. There is no poverty here.
Àsè feast Àsè ìgbéyàwó ni. It is a wedding feast.