ò o ó õ ô ö
Êkö Kçrìndínlögbõn 29 Lesson Twenty Six
Ò O Ó Õ Ô Ö
Page 46
(Four short of fifty)
Ojú-ìwé Kçrìndínláàádöta
Ô Day Ôjö wo nìyìí? What day is this?
Òjò Rain Òjò þ rõ. It is raining.
Owó wà ní ôwö mi. There is money in my hand.
Ô Hand
O Money
Ôyún Pus Ôyún wà lójú egbò yìí. There is pus on this sore.
Oyún Pregnancy Oyún kejì nìyìí. This is the second pregnancy.
Kòkòrò Insect
O Thief
Oko Farm Oko Àdùkë nìyìí. This Aduke’s farm.
Kökörö Key
Ôkô Husband Ôkô Àdùkë nìyìí This is Aduke’s husband.
Õlç ni ó þ di olè. A lazy (person) becomes a thief.
Õ Lazy (person)