Gëgë a ti ÿàlàyé tëlê ojú-ìwé kçwàá, àwôn bátànì sílébù Yorùbá pín sí oríÿìí mëta báyìí:
As previously explained on page ten, there are three syllable patterns in Yoruba as follows:
1 . ( F ) Fáwêlì ( V ) Vowel 2 . ( KF ) Köþþsónáýtì + Fáwêlì (CV) Consonant + Vowel 3 . (M m, N n) Sílébù Àránmúpè (Syllabic Nasal)
A tún fi yé wa pé ó wúlò láti yára ÿe àkíyèsí bí ìhun õrõ pêlú sílébù ÿe þÿisë nípa wíwo àwôn õrõ onísílébù méjì díê. A sì rí bátànì méjì-
It is instructive to quickly note how these syllable building blocks work by illustrating with some bisyllabic (two- syllable) words. Two patterns emerge
1 . F – KF V - CV
a . A - dé b. À - dán ße àkíyèsí pé fáwêlì ìbêrê kò lè jë fáwêlì àránmúpè.
Note that the starting vowel (F, V) cannot be a nasalised vowel.
2 . KF –KF CV-CV
a . Bà-bá b. ßë-gun c. Sàn-yà d . Fun-fun Ní èdè Gêësì, àwôn fáwèlì méjì péré nnínu àlífábëêtì ni o tún lè jë odidi õrõ tí ó ní ìtumõ. Àwôn ni a’ and ‘ i ’. ßùgbön ní èdè Yorùbá, gbogbo àwôn fáwêlì – a, e, ç, i, o, ô, u àti an, çn, in, çn, un ni ó tún lè dá dúró nípò ara wôn gëgë bí odidi õrõ kan nígbà púpõ.
In the English language, only two vowels in the alphabet can represent a meaningful word. They are the letters ‘a’ and ‘ i ’ - as in A boy, I am here In Yoruba, ALL the vowels may stand alone on their own as
ÀWÔN BÁTÀNÌ SÍLÉBÙ SYLLABLE PATTERNS
Page 35
(Five short of forty) Ojú-ìwé Karùndínlógójì