| |
This
web site is for the benefit of all Yorubas at home and abroad
and anyone who loves languages and cultures – especially
Yoruba. |
 |
Ibùdó
orí ìtàkùn àgbáyé yìí wá fún àýfàní gbogbo àwön
ômô ìbílê Yorùbá nílé-lóko àti çnikëni tí ó bá ní
ìfê sí èdè àti àÿà ìbílê –pàápàá ti Yorùbá. |
|
| |
|
|
|
|
| |
Are you of Yoruba ancestry but born abroad
and not proficient enough in speaking the language? |
 |
Ýjë
ômô ìbílê Yorùbá tí a bí sí ìdálê ni ö ÿùgbön tí
kò gbö èdè náà yékéyéké ?
|
|
| |
|
|
|
|
| |
Or you are a foreign-born wife, husband,
relation, friend or acquaintance of a Yoruba? |
 |
Tàbí àjèjì aya, ôkô, çbí, õrë tàbí ojúlùmõ ômô
ilê Yorùbá ni ìwô í ÿe?
|
|
| |
|
|
|
|
| |
Maybe you are Brazilian, Cuban
African-American, Trinidadian or indeed from any part of the
world that can lay claim to an ancestral link to Yorubaland. |
 |
Ó
lè jë ômô orílê-èdè Bràsíìlí, Kúbà, Amëríkà, Trínídáàdì
tàbí ibikíbi ní àgbáyé ni ö ÿùgbön tí o lëtõö sí
ìÿêdálê ilê Yorùbá. |
|
| |
|
|
|
|
| |
Perhaps you are none of the above, but you
just love languages and culture especially Yoruba. |
 |
Bóyá
o kì í ÿe õkankan nínú àwôn wõnyí, ÿùgbön o kàn gbádùn
èdè àti àÿà ìbílë ni, pàápàá ti Yorùbá.
|
|
| |
|
|
|
|
| |
DO YOU WANT TO |
|
ÝJË O
FËË
|
|
| |
Know how to Write it |
|
Mõ
ön kô,
|
|
| |
Know how to Read It ? |
|
Mõ ön
kà ? |
|
| |
Know how to Speak It ? |
|
|
|
| |
|
|
|
|
| |
This
web site will give you a solid foundation for learning the
Yoruba language and also provide you with valuable resources to
enable you become proficient in the language in record time. |
|
Ibùdó orí ìtàkùn yìí yóò fún ô ní ìpilê
tí ó dájú láti kö èdè Yorùbá, yóò sì pèsè àwôn
ohun èlò tí ó wúlò, tí yóò mú ô jáfáfá nínú ìmõ
èdè nàá ní kíá. |
|
| |
|
|
|
|
| |
Learn
Yoruba in Multicolor.
Fi
oríÿìíríÿìí
àwõ kö
Yorùbá. |
|
| |
|
|
|
|