|
A B D E Ç F G GB H I J K |
||
![]() |
||
| FONÓLÖJÌ YORÙBÁ PHONOLOGY | ||
|
|
||
| ÀWÔN ÀMÌ OHÙN ÕRÕ YORÙBÁ | YORÙBÁ INTONATION (ACCENT) MARKS | |
| Ìró ohùn ni òpó èdè Yorùbá. | Yoruba is a "tonal" language.(The tone is the pillar of the | |
| Ó ÿe pàtàkì púpõ láti máa fi àmì | Yoruba language).It is very important to insert accent | |
| sí orí àwôn fáwëêlì õrõ tí a bá kô | marks on words written in the Yoruba language, | |
| ní èdè Yorùbá, kí a sì tún yán àwôn | and to place a dot under the letters that require it. | |
| tí ó bá yç ní ìdí. Bí a kò bá ÿe bëê, | It is very difficult to read and understand the | |
| yóò ÿòro láti kà àti láti mô ìtúmõ-ôn | meaning of sentences if this is not done. | |
| wôn. Àmì ohùn ni a fi þ mô ìyàtõ | ||
| láàárín àwôn õrõ tí ó jô ara wôn. | ||
| Yoruba School | ||
|
L M N O Ô P R S ß T U W Y |
||
| Àmì mëta ni a þ sábàá lò ní èdèe Yorùbá. Àwôn ni | Three intonation marks are commonly used in Yoruba. They are: | |||
| 1. Àmì ohùn òkè ( ) | 1. The acute accent mark ( ) | |||
| 2. Àmì ohùn ìsàlê ( ) àti | 2. The grave accent mark ( ) | |||
| 3. Àmì ohùn àárín ( ). | 3. The middle tone accent mark ( ) | |||
| Õnà tí ó rôrùn láti fi kö pípe õrõ pêlú àwôn àmì yìí ni tí a bá fi wé dídún-un mëta nínú àwôn ohùn tí a þ fi dùrù tàbí pianó tê. Àwôn ohùn náà ni |
The easy way to learn how to pronounce words with these accent marks is to compare them with three of the tones played on the Organ or Piano. These are: |
|||
| dò re mí | do re mi | |||
| A kì í sábà fi àmì ohùn àárín ( x ) sórí õrõ àfi lëêkõõkan lórí i ñ tàbí ð nígbàtí wön bá fara jô fáwëêlì. | The middle tone mark is rarely placed on letters of the alphabet except ocassionally on n and m . | |||
| (dò) ni ohùn ìsàlê, ( re) ni ohùn àárín ( mí ) ni ohùn òkè | The
combination of the "do-re-mi" concept and color-coding will
facilitate learning for beginner and expert alike |
|||
| Copyright Bis Bus International 1997 - 2010 |